Ìsọ̀rí tí orílẹ̀èdè kọ̀ọ̀kan wà ní ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé ọdún 2026 àti pápá tí wọn yóò ti gbá bọ́ọ̀lù

Published
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Ọjọbọ, ọjọ Kọkanla osu kẹfa ọdun 2026 ni idije ife ẹyẹ agbaye ti ọdun yii yoo bẹrẹ.

Awọn orilẹede mejidinlaadọta jakejado agbaye lo n kopa ninu idije naa.

Orilẹede mẹwa si lo n kopa ninu idije ife ẹyẹ agbaye naa lati ilẹ Afirika.

A o ranti pe orilẹede Naijiria ti lulẹ lati kopa ninu idije naa.

Àlàyé rèé lórí ìsọ̀rí tí orílẹ̀èdè kọ̀ọ̀kan wà ní ìdíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé tí ọdún 2026.

Ẹ wa wo awọn orilẹede to n kpa ni isọri A, B, C, D ati bẹẹ bẹẹ lọ.