Lateef Adedimeji, Oboz, àtàwọn òṣèré míì tó gbàmì ẹ̀yẹ ní AMVCA 2026

Oríṣun àwòrán, Instagram/@adedimejilateef/@ihuomalindaejiofor/@buccifranklin
Awọn gbajumọ oṣere tiata, Uzor Arukwe ati Linda Ejiofor lo gba ami ẹyẹ oṣerebinrin ati oṣerekunrin to dantọ julọ nibi eto ami ẹyẹ Africa Magic Viewers' Choice Awards (AMVCA) tọdun 2026.
Ami ẹyẹ Africa Magic Viewers'Choice Award lo jẹ ami ẹyẹ kan to lamilaka fun awọn oṣere nilẹ Africa.
Ni alẹ ọjọ Abamẹta, ọjọ Kẹsan-an, oṣu Karun-un ni ayẹyẹ naa, to jẹ ikejila iru rẹ waye ni ipinlẹ Eko nibi ti ọpọ awọn agbjumọ oṣere tiata kaakiri ilẹ Africa pejupese si.
Lasiko ayẹyẹ AMVCA, oniruuru aṣọ alarambara ni awọn oṣere maa n wọ lọ lati fi ṣe afihan ẹwa ati igbelarugẹ oge ile Africa.
Ni ti ọdun yii, ipele mejilelọgbọn ni wọn gbe ami ẹyẹ naa kale, ti mejidinlogun ninu rẹ si jẹ eyi ti awọn adajọ ti wọn yan lo maa sọ ẹni to gbegba oroke.
Awọn eeyan lo maa dibo lati mu olubori fun awọn ipele yooku.
Gbajugbaja agba oṣere tiata, Joke Silva ni olori awọn adajọ ti ọdun yii.
Fiimu "Gingerrr", To Kill A Monkey", "My Father's Shadow" ati "The Herd" ni wọn akọọle ipele fun ami ẹyẹ to pọ julọ.
Lateef Adedimeji, Bucci Franklin ti ọpọ mọ si Oboz naa gba ami ẹyẹ fun ipa ti wọn ko ninu fiimu Gingerrr ati To Kill A Monkey.
Bakan naa ni wọn ṣe agbekalẹ ipele ami ẹyẹ tuntun lọdun yii fun fiimu ni ede abinibi fun ẹkun ariwa ati aarin gbungbun Africa iyẹn Best Indigenous Language Film for North Africa and Central.
Lara ohun tawọn eeyan tun n sọ nipa ami ẹyẹ naa ni awọn aṣọ alarambara tawọn oṣere to kopa nibẹ wọ, ti imura wọn si jẹ oju ni gbese.
Wo awọn to gba olubori nibi ipele kọọkan ni AMVCA 2026 niyi:
Best Supporting Actor
Simileoluwa Hassan – The Yard
Lateef Adedimeji – Gingerrr
Gabriel Afolayan – Colours Of Fire
Bucci Franklin – To Kill A Monkey - Olubori
Femi Adebayo – King Of Thieves 2
Lateef Adedimeji – Red Circle
Femi Branch – Owambe Thieves
Uzor Arukwe – Behind The Scenes
Best Supporting Actress
Linda Ejiofor – The Herd - Olubori
Olamide Kidbaby – Oversabi Aunty
Bisola Aiyeola – Gingerrr
Sola Sobowale – The Covenant
Nadia Dutch – Aljana
Amal Umar – The Herd
Juliebrenda Nyambura – MTV Shuga Mashariki
Funke Akindele – Behind The Scenes
Best Lead Actor
Mike Ezuruonye – Oversabi Aunty
Lateef Adedimeji – Lisabi: A Legend Is Born
William Benson – To Kill A Monkey
Kanayo O. Kanayo – Grandpa Must Obey
Khumbuza Meyiwa – Bet I Love You
Uzor Arukwe – Colours Of Fire - Olubori
Wale Ojo – 3 Cold Dishes
Femi Branch – Red Circle
Best Lead Actress
Linda Ejiofor – The Serpent's Gift - Olubori
Bimbo Akintola – To Kill A Monkey
Ifeoma Fafunwa – The Lost Days
Ariyike Owolagba – Something About The Briggs
Sola Sobowale – Her Excellency
Scarlet Gomez – Behind The Scenes
Genoveva Umeh – The Herd
Gloria Anozie-Young – Mother Of The Brides
Best Director
Akinola Davies Jr.- My Father's Shadow - Olubori
Tunde Kelani – Cordelia
James Omokwe – Osamede
Daniel Etim Effiong – The Herd
Yemi Filmboy Morafa – Gingerrr
Asurf Amuwa Oluseyi – 3 Cold Dishes
Best Overall Movie
Gingerrr
The Herd
My Father's Shadow - Olubori
3 Cold Dishes
The Serpent's Gift
Behind The Scenes
Best Digital Content Creator
Elozonam Ogbolu, Genoveva Umeh
Akwaman
Destiny Ogie Osarewinda
Emmanuel Kanaga, Sophia Chisom - Olubori
Benedict Ehimare Oriaifo
Taaooma
Steve Chuks
Best Indigenous Language Film (West Africa)
The Serpent's Gift
Lisabi: A Legend Is Born - Olubori
Labake Olododo
Olorisha
Aljana
Best Indigenous Language Film (East Africa)
Inside Job
Sayari
Addis Fikir - Olubori
My Son
Kimote
Best Indigenous Language Film (South Africa)
Bet I Love You
Sebata: The Beast
Ben Made It
Terra Of Queens And Kuma 2
Tlhaho Ya Mosadi - Olubori
Best Indigenous Language Film (North Africa)
The Omnipresent
The Delivery
The Hidden Voice
This Is Portsaid
Artal Alhanin: Our Memories - Olubori
Best Indigenous Language Film (Central Africa)
Mabanda - Olubori
Safou: A Gift From Nature
Golden Spoon
Best Scripted M-Net Original
Adam to Eve
Mother of the Bride
The Yard
The Low Priest - Olubori
Bobo
Best Unscripted M-Net Original
Nigerian Idol S10 - Olubori
Ultimate Girls Trip: Africa
Chapa Chapa My Love
Out N About (Harar)
Undugu
Best Indigenous M-Net Original
Inimba - Olubori
Kukoyi
Undugu
Out N' About (Harar)
Kampala Creme
The Chocolate Empire
Mgbuka
Best Short Film
Fleas
Rise
Telephone
Hussaini - Olubori
My Body, God's Temple
Best Cinematography
Jermaine Edwards – My Father's Shadow - WINNER
Kabelo Thathe – To Kill A Monkey
Emmanuel Igbekele – The Herd
Daanong Gyang – Finding Nina
Emmanuel Igbekele – The Serpent's Gift
KC Obiajulu – Stitches
Emmanuel Igbekele – Gingerrr
Best Editing
Kazeem Agboola – Cordelia
Omar Guzman Castro – My Father's Shadow
Wanguma Peter Chidebere, Dele Doherty – Landline
Asurf Amuwa Oluseyi – 3 Cold Dishes
Winston Aig-Ohioma – Osamede
Daniel Anyiam – To Kill A Monkey - WINNER
Best Sound Design
Pius Fatoke, CJ Mirra – My Father's Shadow - WINNER
Tolu Obanro – Gingerrr
Vaughan Phillips – Ben Made It
Tolu Obanro – The Party
Vaughan Phillips – Sebata: The Beast
Fisayo Adefolaju – The Herd
Best Music Score
Duval Timothy, CJ Mirra – My Father's Shadow - WINNER
Nissi Ogulu – 3 Cold Dishes
Chubb Okobah – Osamede
Tolu Obanro – Gingerrr
Tolu Obanro – The Party
Sofresh – MTV Shuga Mashariki
Oscar Heman-Ackah – To Kill A Monkey
Best Art Direction
Zainab Oladipupo – The Serpent's Gift
Omolade Abisola – The Herd
Ajamolaya Bunmi – Colours Of Fire - WINNER
Olatunji Afolayan, Gideon Stephen – Aljana
Victor Akpan – Suky
Thabiso Senne – Inimba
Best Costume Design
Mary Chukwuma – The Serpent's Gift
Deola Art Alade, Darey Art Alade – The Real Housewives Of Lagos
Valerie Okeke – Colours Of Fire - WINNER
Yolanda Okereke – Something About The Briggs
Ikechukwu Urum, John Joseph Angel – To Kill A Monkey
Best Makeup
Mojisola Imam – Behind The Scenes
Adeola Bamgboye – Lisabi: A Legend Is Born
Dablaq Artistry – Gingerrr
Adeola Bamgboye – Abanisete
Hakeem Effect – Warlord - WINNER
Ruth Harcourt – Suky
Adeola Bamgboye – Labake Olododo
Best Writing TV Series
Donald Tombia, Timendu Aghahowa, Chiemeka Osuagwu – The Wives
Annette Shadeya, Natasha Likimani, Mkamzee Mwatela, Arnold Mwanjila, Makgano Mamabolo – MTV Shuga Mashariki - WINNER
Xavier Ighorodje – Our Husband
Besufekade Mulu – Addis Fikir
Temilola Balogun – Baba Oh
Stephen Okonkwo – The Party
Yednekachew Ayne – Gizat
Best Writing in a Movie
Lani Aisida – The Herd
Wale Davies – My Father's Shadow - WINNER
Ikenna Okpara – Blackout
Shirleen Wangari – Cards On The Table
Xavier Ighorodje – Gingerrr
Isaac Ayodeji – Suky
Tomi Adesina – 3 Cold Dishes
Best Documentary
Beyond Olympic Glory - WINNER
The Good, The Bad of Afrobeat
The People Shall
Not Addressing This Anymore
BOU
Best Scripted Series
To Kill A Monkey
The Yard
The Chocolate Empire
Inimba - WINNER
Kash Money
Best Unscripted Series
The Real Housewives Of Lagos
Nigerian Idol - WINNER
Ultimate Girls Trip: Africa
Offair With Gbemi And Toolz
Out N' About (Harar)
Trailblazer Award
Uche Montana - WINNER
Industry Merit Award
Sola Sobowale - WINNER
Kanayo O. Kanayo - WINNER



























