Ìdíje Madrid, Juventus: Àwọn àwòràn mánigbàgbè

Ronaldo gbá bọ́ọ̀lú (penalty) wọlé
Àkọlé àwòrán, Ronaldo gbá bọ́ọ̀lú (penalty) wọlé
Published

Mario Mandzukic ló kọ́kọ́ gbá góòlù wọlé ní iṣẹ́jú kejì

Mario Mandzukic ló kọ́kọ́ gbá góòlù wọlé ní iṣẹ́jú kejì
Àkọlé àwòrán, Mario Mandzukic ló kọ́kọ́ gbá góòlù wọlé ní iṣẹ́jú kejì

Mario Mandzukic tún jẹ góòlù míràn ní ìṣẹ́jú kẹtàdínlógójì

Mario Mandzukic tún jẹ góòlù míràn ní ìṣẹ́jú kẹtàdínlógójì
Àkọlé àwòrán, Mario Mandzukic tún jẹ góòlù míràn ní ìṣẹ́jú kẹtàdínlógójì
Mario Mandzukic tún jẹ góòlù míràn ní ìṣẹ́jú kẹtàdínlógójì
Àkọlé àwòrán, Mario Mandzukic tún jẹ góòlù míràn ní ìṣẹ́jú kẹtàdínlógójì

Isco góòlù ṣùgbọ́n alamójútó ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa wọ́gilé e

Isco góòlù ṣùgbọ́n alamójútó ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa wọ́gilé e
Àkọlé àwòrán, Isco góòlù ṣùgbọ́n alamójútó ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa wọ́gilé e

Àṣìṣe aṣọ́lé e Real Madrid, Navas fún Juventus láǹfàní láti gbá bọ́ọ̀lù kẹta wọ àwọn rẹ̀

Àṣìṣe aṣọ́lé e Real Madrid, Navas fún Juventus láǹfàní láti gbá bọ́ọ̀lù kẹta wọ àwọn rẹ̀
Àkọlé àwòrán, Àṣìṣe aṣọ́lé e Real Madrid, Navas fún Juventus láǹfàní láti gbá bọ́ọ̀lù kẹta wọ àwọn rẹ̀

Matuidi gbá góòlù kẹta sínú àwọ̀n Real Madrid lati sọ àpapọ̀ góòlù ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ wọn di mẹ́ta-mẹ́ta, 3-3.

Matuidi gbá góòlù kẹta sínú àwọ̀n Real Madrid
Àkọlé àwòrán, Matuidi gbá góòlù kẹta sínú àwọ̀n Real Madrid lati sọ àpapọ̀ góòlù ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ wọn di mẹ́ta-mẹ́ta, 3-3

Alamójútó ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa Oliver lati ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì pè fún gbé e siílẹ̀ ko gba sílé lẹ́yìn tí Benatia (Juventus) ti Vazquez (Real Madrid) lójú ilé

Alamójútó ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa Oliver lati ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì pè fún gbé e siílẹ̀ ko gba sílé lẹ́yìn tí Benatia (Juventus) ti Vazquez (Real Madrid) lójú ilé
Àkọlé àwòrán, Alamójútó ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa Oliver lati ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì pè fún gbé e siílẹ̀ ko gba sílé lẹ́yìn tí Benatia (Juventus) ti Vazquez (Real Madrid) lójú ilé

Alamójútó ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa Oliver lati ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì lé aṣọ́lé Juventus, Gianluigi Buffon fun sísọ̀rọ̀ òdì sí alamójútó ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa

Alamójútó ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa Oliver yọ káàdì pupa sí aṣọ́lé Juventus, Gianluigi Buffon fun sísọ̀rọ̀ òdì sí alamójútó ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa
Àkọlé àwòrán, Alamójútó ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa Oliver lati ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì lé aṣọ́lé Juventus, Gianluigi Buffon fun sísọ̀rọ̀ òdì sí alamójútó ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ naa

Ronaldo gbá bọ́ọ̀lú (penalty) wọlé

Ronaldo gbá bọ́ọ̀lú (penalty) wọlé
Àkọlé àwòrán, Ronaldo gbá bọ́ọ̀lú (penalty) wọlé

Àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù tí yóò kópa ní ipele to kangun si aṣekagba

Àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù tí yóò kópa ní ipele to kangun si aṣekagba
Àkọlé àwòrán, Àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù tí ko leè kópa mọ́ ní ipele to kangun si aṣekagba

Àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù tí opin de ba irinajo wọn

Àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù tí opin de ba irinajo wọn
Àkọlé àwòrán, Àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù tí opin de ba irinajo wọn