Èyí ni àkójopọ̀ èsì ìdìbó gómìnà láti ìpínlẹ̀ Osun

Published
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1
Bi idibo si ipo gomina nipinlẹ Osun ṣe waye lọjọ Abamẹta, ọjọ kẹẹẹdogun oṣu Kẹjọ ọdun 2026 yii ni ajọ eleto Idibo ilẹ wa, INEC, ṣe ti n ko esi ibo naa jọ.
Bẹẹ naa si ni BBC News Yoruba to ti gunlẹ sipinlẹ Osun ṣaaju ọjọ idibo n mu gbogbo ẹ wa bo ṣe n lọ.
Eyi ni awọn esi idibo naa bi wọn ṣe n jade lati ijọba ibilẹ kọọkan l'Osun.
Lati maa mọ bi esi idibo naa ṣe n lọ si, ẹ maa ba wa bọ lori ikanni ati oju opo yii.























