Àwọn epo pupa kan wà níta báyìí tó lè fa àìsàn jẹjẹrẹ, wo bí o ṣe lè dá a mọ̀
Àwọn epo pupa kan wà níta báyìí tó lè fa àìsàn jẹjẹrẹ, wo bí o ṣe lè dá a mọ̀
Published
Njẹ o ti gbọ wi pe awọ̀n epo pupa buruku kan to le ṣe akoba fun agọ ara eeyan ti wa nita bayii?
Ileeṣẹ to n ris si abo ounjẹ fun araalu ni ipinlẹ Eko, LASCOPA lo pariwo ọrọ yii sita lẹyin ti ọjọgbọn kan, Ọmọwe Nura Oseni ti kọkọ ṣekilọ nibi eto idanilẹkọ pe oniruuru awọn adalu to lewu fun ilera ara lawọn eeyan kan ti n da pọ mọ epo pupa kaakiri bayii lọna ati le mu ko pọ sii tabi pupa yoo.
Wo fidio yii siwaju sii lati mọ ohun to yẹ ki o ṣe lati bọ lọwọ lilugbadi irufẹ epo wọnyii.





