AI ni wọ́n fi ṣe fọ́tò mi pé mo ṣe ìpàdé pẹ̀lú Sheik Gumi, n kò sí níbi ìpàdé náà - Oriyomi Hamzat

Àkọlé fídíò, AI ni wọ́n fi ṣe fọ́tò mi pé mo ṣe ìpàdé pẹ̀lú Sheik Gumi, n kò sí níbi ìpàdé náà - Oriyomi Hamzat
AI ni wọ́n fi ṣe fọ́tò mi pé mo ṣe ìpàdé pẹ̀lú Sheik Gumi, n kò sí níbi ìpàdé náà - Oriyomi Hamzat
Published

Oludije fun ipo gomina ipinlẹ Oyo lọdun 2027 ninu ẹgbẹ Accord, Oriyomi Hamzat, ti ṣalaye ero ọkan rẹ ati idi to fi fẹ di gomina fun BBC, bẹẹ lo ṣe adehun fun awọn eeyan ipinlẹ Oyo.

Oriyomi sọ pe oun ti won ti mọ tẹlẹ naa ni, oun ko ni i yipada si ai daa fun wọn bi won ba fibo yan oun sipo.

Ninu ifọrọwerọ pẹlu Hamzat lo ti ṣalaye ajọṣepọ rẹ pẹlu gomina akọkọ to ni oun kọkọ ba ṣe nipinlẹ Oyo, iyẹn Rashidi Adewolu Ladoja, lẹyin ẹ lo ni oun ba Ajimobi ṣe, Alao Akala ni saa akọkọ rẹ ati Seyi Makinde.