Bí mo bá rántí bí Nàìjíríà ṣe bẹ̀rẹ̀, ó máa ń dùnmí gán ní, àìní sùúrú kóbá wa – Yemi Farombi

Àkọlé fídíò, Bí mo bá rántí bí Nàìjíríà ṣe bẹ̀rẹ̀, ó máa ń dùnmí gán ní, àìní sùúrú ló kóbá wa – Yemi Farombi
Bí mo bá rántí bí Nàìjíríà ṣe bẹ̀rẹ̀, ó máa ń dùnmí gán ní, àìní sùúrú kóbá wa – Yemi Farombi
Published

Alagba Yẹmi Farounbi ṣalaye pe eyi ti ologun da silẹ lara ohun to n ṣe Naijiria pọ pupọ.

Ninu ifọrọwerọ rẹ nipa irinajo Naijiria lati ibẹrẹ igbominira rẹ titi di asiko yii, o ni ohun to maa n ba oun ninu jẹ ni ipo ti orilẹede Naijiria ba ara rẹ loni jẹ eyi to maa n ba oun ninu jẹ pupọ julọ.