Wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ ìbò kíkà níbí ètò ìdìbò Gómìnà ìpínlẹ̀ Ekiti

Awọn oṣiṣẹ ajọ eleto idibo INEC n ka ibo
Published
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Igbesẹ kika iye ibo tawọn eeyan di ti bẹrẹ kaakiri ibudo idibo gomina ni ipinlẹ Ekiti.

Nnkan bi ọwọ aago meji abọ ọsan ni ibo kika naa gberasọ lati ọwọ awọn oṣiṣẹ ajọ eleto idibo INEC.