Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ijọba apapọ ti sọ pe ko nilo ki Aarẹ Naijiria wa niluu Abuja ko to le ṣiṣẹ ti araalu yan an fun
Ọrọ yii lo n jẹyọ lẹyin ti Aarẹ Bola Tinubu lọ fun isinmi lẹnu iṣẹ amọ ti ko gbe agbara silẹ fun igbakeji rẹ
BBC kan si agbẹjọro kan, Victor Opatola lati tan imọlẹ si ọrọ naa
Ohun to sọ wa loju opo BBC Yoruba
*****************************************************************
Ileeṣẹ ọlọpaa ti bẹrẹ iwadii lori awọn to ni agbari ati egungun eeyan bii mejidinlọgbọn ti wọn ri lakata awọn afurasi kan nipinlẹ Abia
A gbọ pe pe agbegbe Isuochi to wa ni ijọba ibilẹ Umunneochi ni wọn ti ri awọn agbari naa
Ọlọpaa ni o ṣeeṣe ki awọn agbari naa jẹ ti awọn ti wọn ji gbe amọ iwadii n lọ lọwọ
******************************************************************
Nilẹ Gẹẹsi
Ọwọ ọlọpaa ti tẹ afurasi maru un lori ẹsun igbesunmọmi
Lẹyin ibugbamu kan to waye lẹba ibudo awọn ọmọ ogun ofurufu lagbegbe Gloucestershire (GLOST-ər-shər)
To ba fẹ mọ ẹkunrẹrẹ


