Oronna, jagunjagun tó gbéra láti Oyo lọ tẹ ìlú Ilaro dó
Oronna, jagunjagun tó gbéra láti Oyo lọ tẹ ìlú Ilaro dó
Published
Ilu Ilaro jẹ ọkan lara awọn ilu to gbajugbaja nilẹ Yoruba lode oni.
Gẹgẹbi awọn eeyan ṣe sọ, Ilu Aro ni orukọ rẹ ni ibẹrẹ pẹpẹ, amọṣa apetunpe ọjọ pipẹ lo mu ki o di Ilaro.
Gẹgẹbi ọrọ ti Arabinrin Ọmọlara Akintade, Iya Eto ilu Ilaro ba BBC News Yoruba sọ, ọkan lara awọn ọmọ-ọmọ ọba ilu Ọyọ ti wọn n pe ni Aro lo kuro niluu Ọyọ lati wa tẹ ilu naa do.
"Amọ'sa nigba ti ogun awọn idaọmi n daa laamu lo pe Oronna lati wa ba oun sọ agbegbe ibi to tẹdọ si to tuu lara."
Alaye bi Ilu Ilaro ṣe duro wa ninu fidio yii.





