Mọ iye ọdún tó ṣeéṣe kí o lò láyé

Published

Njẹ́ o mọ̀ pé iye ọdún tó ṣeéṣe kí gbogbo ènìyàn yóò lò láyé ti fi ọdún méje pọ̀ si láti 1990?

Irinṣẹ́ òǹkà yìí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣe ìṣìrò tìrẹ̀ ní ìbámu pẹ̀lú orílẹ̀èdè tí o ti wá.

Ọdun mejilelaadọrin nireti wa pe o jẹ ọdun to kere ju ti ẹda yoo lo laye - aadọrin ọdun fun ọkunrin, marundinlọgọrin fun obinrin. Ṣugbọn, eyi n yipada pẹlu ọjọ ori. Fun apẹẹrẹ,ireti wa pe ẹni ti o ti pe ọdun mọkandinlaadọrin yoo lo ọdun mẹtadinlogun si.

Fo Móríwú kọjá kí o tẹ̀síwájú

Móríwú

  • Omowunmi Dada wọ asọ alawọ ofeefe, o lo irun oloyinbo to gun de aya rẹ, o joko sori aga, so ọwọ rẹ mejeeji papọ
  • Sharafadeen Abiodun Alli
  • Suliat Abideen wọ asọ ere idaraya, o kun irun ori rẹ ni awọ pupa
  • Taiwo Oyedele wọ asọ kootu oyinbo, shaati funfun ati tai pupa
  • Amina Mohammed wọ asọ leesi alawọ buluu ati gele alawọ omi aro
  • Oogun oloro ninu epo pupa
  • Taofeek Adegoke wọ asọ toketilẹ alawọ buluu ati fila asọ oke buluu, o so ọwọ rẹ mejeeji papọ
  • Ọkunrin to bọ lọwọ ajinigbe wọ asọ toke tilẹ ati fila alawọ ewe
  • Agubanirọ naa wọ asọ buluu, da sikafu bo ori de ọrun, o lo awo dudu, fi nnkan we ẹnu
  • Danladi wọ asọ ibilẹ alawọ buluu ati fila rẹ
  • Amina Eleha wọ kaba aláwọ̀ búlúù, ó sì ṣe irun dídì gbọọrọ
  • Gomina Aiyedatiwa wọ aṣọ shaati funfun, ó dé fìlà aláwọ̀ buluu

Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ