Níbo Layé Kọjú Sí?: Kí lobìnrin ń fẹ́ lára ọkùnrin gan? Eyiyemi Afolayan dá sí ìbéèrè yí
Níbo Layé Kọjú Sí?: Kí lobìnrin ń fẹ́ lára ọkùnrin gan? Eyiyemi Afolayan dá sí ìbéèrè yí
Published
Ki lawọn obinrin n wa lara ọkunrin gan ki wọn to le sọ pe iru ọkunrin yii gan an lo dara fun awọn?
Eyiyẹmi ọmọ gbajumọ elere itage ni Afọlayan ṣalaye iru nnkan to n fẹ ninu ọkunrin. o ni ifẹ wa lara amuyẹ ti oun a wo ki oun to fẹ ọkunrinrin o, ṣugbọn oun ko le fẹ ọkunrin ti ko ni iṣẹ lapa rara.
"Lootọ abọlanle ni mi, ọkọ ti mo ba n fẹ gbọdọ ni nnkan to n ṣe funrarẹ, mi o le maa bọ ọkunrin.'
Eyi atawọn nnkan miran lo wa ninu eto nibo laye kọju si ọtẹ yii.





