'Mi ò rò péToluwanisings lè kú lọ́gbọ̀n ọdún sí àsìkò yìí ṣùgbọ́n...' - Àwọn ọ̀rẹ́ ìpìlẹ̀ Toluwanisings ṣàlàyé àwọn ohun tó ń pinnu kí ikú tó dé
'Mi ò rò péToluwanisings lè kú lọ́gbọ̀n ọdún sí àsìkò yìí ṣùgbọ́n...' - Àwọn ọ̀rẹ́ ìpìlẹ̀ Toluwanisings ṣàlàyé àwọn ohun tó ń pinnu kí ikú tó dé
Published
Se ni awọn ọrẹ igba ewe, alabagbele atawọn aladugbo ni agbegbe Olanbe nipinlẹ Ogun to ti ja pọ mọ ipinlẹ Eko, pejọ lati se ẹyẹ ikẹyin pẹlu abẹla titan fun gbajumọ akọrin ẹmi Olayemi Bayonle Bolaji, ti ọpọ eeyan mọ si Toluwanisings.
Ohun ti ọpọlọpọ wọn n sọ ni pe ẹni ti atigoke rẹ nira diẹ ni, ṣugbọn ko tori eyi gbagbe ipilẹ rẹ.
Ninu ọrọ ti ọkan ninu wọn ba BBC News Yoruba sọ, igbaradi fun ajọyọ ipadabọ si adugbo to gbe dagba ni wọn n mura lọwọ ko to di wi pe iroyin iku rẹ de wa ba wọn ni adugbo Labẹ nibi ti o ti ṣe akoko ewe rẹ.
Ẹkunrẹrẹ iroyin yii wa ninu fidio yii.





