Àjọ NDLEA ri oogun oloro Skunk ninu kẹẹgi to kun fun epo pupa
Àjọ NDLEA ri oogun oloro Skunk ninu kẹẹgi to kun fun epo pupa
Published
Gẹgẹ bi ajọ NDLEA naa se wi, awọn ọmọ aye kan lo pari idan yii, wọn ko ẹya oogun oloro ta a mọ si Skunk sinu kẹẹgi.
Wọn fẹẹ gbe e kọja sorilẹede Saudi Arabia, ni ọwọ ajọ NDLEA to n ri si oogun oloro tẹ wọn ni papakọ ofurufu Mallam Aminu Kano.
Eyi tun gbẹnu tan o!



