'Mo fẹ́ bá àwọn tí kò bọ̀wọ̀ fún mi wí láì lo ẹgba' Gbajúmọ̀ òṣèré', Nkechi Blessing sọ̀rọ̀ ṣáàjú ẹ̀ṣẹ̀ kíkàn tó fẹ́ jà pẹ̀lú Phyna
'Mo fẹ́ bá àwọn tí kò bọ̀wọ̀ fún mi wí láì lo ẹgba' Gbajúmọ̀ òṣèré', Nkechi Blessing sọ̀rọ̀ ṣáàjú ẹ̀ṣẹ̀ kíkàn tó fẹ́ jà pẹ̀lú Phyna
Published
Lẹnu ọjọ mẹta yii awọn ilumọọka ti n ya si lilo ere idaraya gẹgẹ bi ọna idaraya kan. Ṣaaju asiko yii ni awọn eekan bii Charles Okwocha, Portable, Catar Efe atawọn eekan miran ni wọn ti koju ara wọn ni gbagede ere idaraya ẹṣẹ kikan.
Nibayii, ọrọ naa ti wa kan awọn obinrin pẹlu bi gbajumọ oṣerebinrin, Nkechi Blessing naa ti fẹ wọ gbagede ẹṣẹ kikan pẹly Phyna Otabor.
Awọn mejeeji ṣalaye ninu fọnran yii lori igbaradi wọn ati ipa ti ija wọn naa yoo mu ba ifẹ awọn obinrin fun ere idaraya, paapaajulọ ẹṣẹ kikan.