Àwọn aṣọ aláràmbarà tí wọ́n lò níbi ayẹyẹ AMVCA

Àkọlé fídíò, AMVCA
Àwọn aṣọ aláràmbarà tí wọ́n lò níbi ayẹyẹ AMVCA

Niṣe ni itọ le fẹ ẹ maa da lẹnu eeyan pẹlu iran wiwo nibi ayẹyẹ AMVCA, Ami ẹyẹ Africa Magic Viewers'Choice Award to jẹ ami ẹyẹ kan to lamilaka fun awọn oṣere nilẹ Africa.

Bi a se ri awọn to fi fere ran aṣọ, ni awọn mii lo kaninkanin irin, pabambari rẹ ni ẹni to lo burẹdi.

Ẹ fun oju lounjẹ.