Bí o bá ń pẹ́ kí o tó sùn lálẹ́, ewu ń bẹ fún ìlera ọpọlọ rẹ

Àkọlé fídíò, Bí o bá ń pẹ́ sùn lálẹ́, ó léwu fún ìlere ọpọlọ rẹ
Bí o bá ń pẹ́ kí o tó sùn lálẹ́, ewu ń bẹ fún ìlera ọpọlọ rẹ
Published

Bi o ba n pẹ ki o to sun lalẹ, ewu nla lo jẹ fun ilera ọpọlọ rẹ.

Iṣẹ iwadi ajọ imọ ilera ọpọlọ kan to waye laipẹ yii lo fi idi rẹ mulẹ pe ẹni to ba n pẹ sun bi agogo mẹwaa si mejila tabi agogo kan oru ṣeeṣe ko ni ipenija ọpọlọ lọjọ iwaju.

Iwadii naa sọ sọ awọn to ba n pẹ sun lalaalẹ maa n ronu ju bi o ti ṣe yẹ lọ pẹlu irẹwẹsi ọkan. Bakan naa ni iwadii ọhun tun fidi rẹ mulẹ pe bẹẹ ni aya wọn yoo tun maa ja.